15880. Gba Aiye Mi Oluwa

1 Gba aiye mi oluwa,
Mo ya si mimo fun O
Gba gbogbo akoko mi
Ki nwon kun fin iyin Re.

2 Gba owo mi, k’o si je
Ki nma lo fun ife Re;
Gba ese mi, k’o si je
Ma jise fun O titi

3 Gba ohun mi, je ki nma
Korin f’oba mi titi;
Gba ete mi, je ki wom
Ma jise fun o titi.

4 Gba wure, fadaka mi
Okan nki o da duro;
Gba ogbon mi, ko si lo
Gege bi o ba ti fe.

5 Gba ’fe mi. fi se Tire;
Kio tun je temi mo;
Gb’ okan mi, Tire n’ ise
Ma gunwa nibe titi.

6 Gba ’feran mi, Oluwa
Mo fi gbogbo re fun O
Gb’emi papa; lat’ one
Ki’m je Tire titi lai.

Text Information
First Line: Gba aiye mi oluwa
Title: Gba Aiye Mi Oluwa
English Title: Take my life and let it be
Author: Frances R. Havergal
Meter: 77.77
Language: Yoruba
Copyright: Public Domain
Tune Information
Name: ST. BEES
Composer: John Bacchus Dykes
Meter: 77.77
Key: A♭ Major
Copyright: Public Domain



Media
Adobe Acrobat image: PDF
MIDI file: MIDI
Noteworthy Composer score: Noteworthy Composer Score
More media are available on the tune authority page.

Suggestions or corrections? Contact us