15878. E Maa Te Siwaju, Kriatian Olugun

1 E maa te siwaju, Kriatian ologun
Maa tejumo mo Jesu t’o mbe niwaju;
Kristi Oluwa wa niBalogun wa
Wo! asia re wa niwaju ogun.

Egbe:
E ma te siwaju Kristain ologun
Sa tejumo Jesu t’o mbe niwaju.

2 Ni oruko Jesu ogun esu sa,
Nje Kristian ologun, ma nso si segun;
Orun apadi mi ni hiho iyin
Ara gbohun yin ga, gb’orin yin soke. [Egbe]

3 Bi egbe ogun nla, n’Ijo Olorun,
Ara, a nrin l’ona t’awon mimo
A ko ya wa n’ipa, egebe kan ni wa
Okan L’eko n’ife ati n’ireti. [Egbe]

4 Ite at’ijoba wonyi le parun,
Sugbon Ijo jesu y’o wa titi lai,
Orun apadi ko le bor’ ijo yi
A n’ileri Kristi, eyi ko le ye. [Egbe]

5 E ma ba ni kalo, eyin eyan;
D’ohun yin po mo, lorin isegun,
Ogo, iyin, ola fun Kristi Oba
Eyi ni y’o ma je orin wa titi. [Egbe]

Text Information
First Line: E maa te siwaju, Kriatian ologun
Title: E Maa Te Siwaju, Kriatian Olugun
English Title: Onward, Christian soldiers
Author: Sabine Baring-Gould
Translator: Anonymous
Refrain First Line: E ma te siwaju Kristain ologun
Meter: 11.11.11 D
Language: Yoruba
Copyright: Public Domain
Tune Information
Name: ST. GERTRUDE
Composer: Arthur Seymour Sullivan (1871)
Meter: 11.11.11 D
Key: E♭ Major
Copyright: Public Domain



Media
Adobe Acrobat image: PDF
MIDI file: MIDI
Noteworthy Composer score: Noteworthy Composer Score
More media are available on the tune authority page.

Suggestions or corrections? Contact us